'Nígbà tí mò ń wà Awolowo, Gowon, Babangida, mo fi ara mi sípo ọ̀wọ̀ tóri ...'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Pa Olabode Olajide: Pé Osinbajo wá kí mi ló mú inú mi dùn jù nílé ayé mi

Baba Olabode Olajide ni awakọ to wa ọpọlọpọ awọn aṣaaju orilẹede Naijiria.

Ni gbogbo akoko to fi wa wọn, ko si eyi ti ko ranti ninu wọn to fi mọ igba ti awọn adari orilẹede mii lagbaye naa ba wa ṣe ibẹwo si awọn ti Naijiria.

Bo tilẹ jẹ pe baba Olajide ni awọn obi ko ri owo tọ ọ kọja ile iwe alakọbẹrẹ, o tiraka lati sọ ara rẹ di akọṣẹmọṣẹ ninu iṣẹ awakọ lai mọ wi pe eyi yoo sọ oun di mọlumọka to di lonii.

Related Topics