Òjò àrọ̀ọ̀rọ̀dá: Àwòrán káàkiri ìlú arómi-sá-lẹ̀gbẹlẹ̀gbẹ
Iṣẹ́ òòjọ́ ṣebi ẹni dẹnu kọlẹ̀ l'Ékòó pẹlu ayagbayamu ojo to rọ lowurọ ọjọ aje. Aworan ti ẹ fi sọwọ si wa re e.

Oríṣun àwòrán, SUNDAY MICHEAL OGWU
Adugbo CMS ni Sunday Micheal Ogwu ti fi aworan yi sọwọ
Oríṣun àwòrán, Sunday Micheal Ogwu
Ojo naa mu sunkẹrẹ fa kere ọkọ wa
Bi oju ọjọ ṣe ri re ki ojo naa to bẹrẹ ladugbo Ogudu
Ọrọ di boo lọ o ya n mi ladugbo Ikoyi
Oríṣun àwòrán, Ayanfhe Eledumare Ololade
"Ọlọrun lo n dara... Yara mi ti kun fun agbara ojo..."
Oríṣun àwòrán, Adedoyin O'Chile Adeyemmy
Oju ojo mọle kedere ni ọdọ tawọn kan lorileede CYPRUS nitoripe igba oorun ti awon oloyinbo n’pe ni “Summer” ni wọn wa
Òjò náà ló ti fa súnkẹrẹ fàkẹrẹ ọkọ̀ lójú pópó ní agbègbè Abiola Garden
Oríṣun àwòrán, Oluwatimilehin Faremi Anani
Ojo n ro gidigidi ni adugbo tia ni Agric, Ikorodu
Oríṣun àwòrán, Olatunde Lawal
Ni igboro ilu Eko(Lagos island)aroroda ni ojo na n ro bayi