Ìdílé tó gba olùkọ́ èdè Yorùbá fún àwọn ọmọ nílẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Yoruba: Mi ò fẹ́ kí àwọn ọmọ má gbọ́ èdè Yorùbá níbi tí a wà yìí

Torin tijo tilu ni wọn fi n kọ ede Yoruba.

Gẹgẹ bi awọn olukọ kilaasi alakọbẹrẹ ṣe maa n kọ awọn ọjẹ wẹwẹ ni àwọn obi yii atawọn ọmọ wọn ṣe di ọmọ kilaasi kan naa lati le kọ ede Yoruba.

Iya awọn naa ni ko rọrun lati kan maa dagba nilẹ Gẹẹsi lai ni iwuri ibi ti o ti ṣẹ wa gan.

Eyi lo mu ko gbe igbesẹ lati gba olukọ ede Yoruba fun awọn ọmọ rẹ.