Ǹjẹ́ kíkọ́ ‘Will’ pọn dandan fún ènìyàn?
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Will: Àwọn olùgbé Eko ni ẹni tó ní owó, ló ń ṣe àkọsílẹ̀ ìlànà ogún pínpín

Awọn ọmọ Naijiria ti fi ero wọn han lori ipa pataki ti kikọ ‘will’ nni lori igbe aye awọn eniyan.

Ọpọlọpọ awọn to fi ero wọn han ni sọ pe awọn olowo nikan lo le kọ will nitori awọn lo ni dukia ti wọn fẹ pin.

Amọ awọn ẹlomiran gbagbọ wi pe, ẹkọ iwe lo se pataki gẹgẹ bi ogun ti eniyan le fi silẹ fun ọmọ.

Awọn iroyin miran ti ẹ ni ifẹ sii: