Nigeria swearing-in 2019: Wo àwòrán tó jẹ ojú ní gbèsè nípa ìbúra ààrẹ àtàwọn gómìnà

Aṣọ ń pe aṣọ ránṣẹ́
Àkọlé àwòrán Gele mi ga ju tiẹ lọ lawọn obinrin fi ibura se ni Naijiria

E wo akojọpọ awọn iroyin to lamilaaka nipa ibura awọn gomina ati aarẹ:

Olu-ilu Naijiria, Abuja:

Abuja
Àkọlé àwòrán Igba ọtun wọle de, ọmọ Naijiria, Aarẹ Muhammadu Buhari lo sọ bẹẹ bo se n bẹrẹ saa keji pẹlu iburawọle
Igbakeji aarẹ Yemi Osinbajo naa se ibura Image copyright VON
Àkọlé àwòrán Igbakeji aarẹ Yemi Osinbajo naa se ibura
Abuja
Àkọlé àwòrán Oye naa tun ko sile wa lẹẹkeji. Orin yii ni awọn eeyan n kọ bi Buhari se n kọja lọ
Olori ile igbimọ Asoju sofin, Aarẹ ile igbimo Asofin Agba, Bukola Saraki naa pejupesẹ si ibi iburawọle.
Àkọlé àwòrán Bi a ko ba gbagbe ọrọ ana, a kii ri ẹnikan a ba ṣere.

Ipinlẹ Eko:

Lagos
Àkọlé àwòrán Gomina sanwo-olu ti ipinlẹ Eko ati ẹbi rẹ.
Lagos
Àkọlé àwòrán Awọn ara Eko pejọ si ibi iburawọle fun Gomina tuntun ati igbakeji rẹ.
Eko
Àkọlé àwòrán Igbakeji gomina tuntun ni ipinlẹ Eko ati mọlẹbi rẹ.
Ojo pa Sanwo-olu lasiko ibura
Àkọlé àwòrán Ọwọ ẹrọ ni ibura gomina mu dani ni Eko, Ojo wẹliwẹli rọ le gomina Sanwo-Olu lori
EKO
Àkọlé àwòrán Sokoto penpe ọlọpaa, a fi bii igba ti Naijiria ko i tii gba ominira
Lagos
Àkọlé àwòrán Olori eto ẹsọ alaabo ni ipinlẹ Eko di ihamọ ogun wọ.

Ipinlẹ Oyo

Oyo
Àkọlé àwòrán Onimọẹrọ Ṣeyi Makinde ati igbakeji rẹ, Rauf Olaniyan ti bura wọle gege bii gomina ati igbakeji gomina ipinlẹ Ọyọ
Oyo
Àkọlé àwòrán Gomina tuntun naa nipinlẹ Oyo ni oun ni imọ rere fun awọn ara ilu
Rauf Aderẹmi Ọlaniyan ree to n se ibura niduro pẹlu aya ati ọmọbinrin rẹ
Àkọlé àwòrán Igbakeji gomina Oyo, Rauf Aderẹmi Ọlaniyan ree to n se ibura niduro pẹlu aya ati ọmọbinrin rẹ
Oyo
Àkọlé àwòrán Ẹgbẹ olorin ni ipinlẹ Ọyọ fi ijo ati ayẹ̀yẹ pada gomina tuntun ni ipinlẹ naa.
Oyo
Àkọlé àwòrán Awọn ara ipinlẹ Oyo naa tu yaya tu yaya si gbagede ibi ti wọn ti se iburawọle fun gomina tuntun naa.

Ipinlẹ Kwara

Ilorin
Àkọlé àwòrán Awọn ara ilorin naa ko gbẹyin ni ibi iburawọle naa
Kwara
Àkọlé àwòrán Igbakeji Gomina tuntun ati iyawo re ni ipinlẹ Kwara
Ilorin
Àkọlé àwòrán Emir ti ilu Ilorin, Zulu Gambarie naa ko gbẹyin ni ibi iburawọle to waye.
Ilorin
Àkọlé àwòrán Gomina ipinlẹ Kwara tuntun ati iyawo rẹ wọle.
Awon ebi ati ore
Àkọlé àwòrán Aṣọ ń pe aṣọ ránṣẹ́ ni lásìkò ìbúra gómìnà àti ààrẹ

Akojọpọ awọn aworan yii wa lati ile isẹ BBC ati Twitter