Sayeed Osupa dá sí ọ̀rọ̀ Barrymade àti KWAM1
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Barrister lo bi gbogbo oníṣẹ́ fújì -Oṣupa

Kollington Ayinla naa jẹ baba fun gbogbo ẹni to ba ṣoriire nidi Fuji- Osupa.

Barrymade ọmọ Barrister to jẹ oloogbe ti ọpọ n bu ọla fun ni olorin fuji lo tahun si King Wasiu Ayinde Marshal.

Lẹyin eyi ni K1 naa dahun pe agba ko kan ọgbọn.

Ọrọ yii n ja ranyin nilẹ to n bi oriṣiiriṣii nkan lori ayelujara.

Lori ọrọ yii naa ni Alhaji Sayeed Osupa fi ero tirẹ hàn si fun BBC Yorùbá.

Oṣupa sọrọ lori ọna abayọ si ọjọ iwaju fuji ni Naijiria.