Ọ̀rọ̀ òṣèlú Sudan ti ń gbẹbọ lọ́wọ́ tẹrútọmọ báyìí
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Omar Al-Bashir ti wọ́n gbajọba lọ́wọ́ ẹ ló di wàhálà

Iroyin ni ẹ̀mí mẹjọ lo ti lọ sinu iwọde naa.

Gbigba ti wọn gba ijọba lọwọ aarẹ Omar al Bashir loṣu kẹrin ati ọrọ dida ijọba pada fawọn alagbada lo n fa wahala ni Sudan bayii.

Loju awọn kan, awọn ologun ti n fẹsẹ falẹ lati mu ileri wọn sẹ lasiko yii.

Opọlọpọ lo kọkọ dunnu pe ologun gba ijọba pẹlu ileri lati tete gbe igbesẹ lati daa pada fawọn alagbada.

Awọn ologun da ibọn bolẹ lati fi fopin si iwọde ti awọn eniyan Sudan n ṣe yii.

Iroyin kan ni o ti to ẹmi awọn eniyan mẹjẹ to ti lọ si iwọde yii ni Sudan.

Ikilọ: Awọn aworan to le bani lẹru han ninu fọnran yii.