South Africa: Inú mi dùn pé mò ń lọ ife ẹ̀yẹ àgbáyé- Janine Van Wyk
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Janine Van Wyk: Lẹ́yìn ọdun mẹ́rìnlá ti mó ti gbà bọ́ọ̀lù, mó ń lọ fún ife ẹ̀yẹ àgbáye

Janine Wyk tó jẹ́ agbábọọlu obìnrin ní orílẹ-èdè South Africa, sọ gbogbo ìr'\inri rẹ̀ lásìkò tó bẹ̀rẹ̀ sí ni gbá bọ́ọ̀lu gẹ́gẹ́ bi obinrin.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: