‘Ojú ọ̀nà Ibadan sí Ife ti bàjẹ́ pátápátá!’ - Awako
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ibadan-Ilesa Road: Àwọn olè Fulani ló ń jí ènìyàn, pànìyàn ní lọ́nà Ibadan sí Ileṣa

Àìda márosẹ̀ Ibadan sí Iléṣà ló ń fa ìjínigbé àti ìdigunjalè - Àwọn awakọ̀ fárígá

Iroyin lori eto abo to mẹhẹ ni opopona Ibadan si Ife fi lede wi pe awọn Fulani darandaran pa arinrinajo kan to n lọ si ilu Ibadan.

Eyi ko sẹyin eto aabo to mẹhẹ lorilẹede Naijiria pẹlu ijinigbe ati ipaniyan ni awọn opopona kaakiri orilẹede Naijiria.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Awọn awakọ, ẹrọ to n naa popona naa sọrọ lori awọn ohun ti oju wọn n ri lasiko ti awon adigunjale ba n sọsẹ ni awọn ọna naa.

Bakan naa ni wọn wa rọ ijọba lati ba wọn se atunsẹ oju ọna naa ti o ti bajẹ patapata.