Àwọn èèyàn tó ṣòfò dúkìá nínú ìjàmbá iná n‘Ibadan ń pariwo fún ìrànwọ́
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Iná Ibadan: Gbogbo dúkìá tó wà lókè ilé alájà kan náà ló jóná tán

Lasiko ti wọn n ba BBC Yoruba sọrọ, awọn olugbe inu ile naa rawọ ẹbẹ si awọn ẹlẹyinju aanu ọmọ ilẹ yii lati se iranwọ fun wọn, lori awọn dukia wọn to jona mọle.

Wọn salaye pe, awọn gbiyanju lati sare ko awọn ohun elo to n bẹ ninu ile naa jade lasiko ti eefin bẹrẹ sini ru.

Sugbọn wọn ni pupọ ninu awọn ohun elo naa ni ina ọmọ ọrara ti sọ di eeru, ki awọn aladugbo to gbe omi ati awọn ohun elo mii ti wọn fẹ fi pa ina to de.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: