Kàyééfì Promo: Ìyá, ọmọ tuntun àti olubi ló wà níbùdó ìgbókùsí, àmọ́ òkú ọmọ di àwátì

Kàyééfì Promo: Ìyá, ọmọ tuntun àti olubi ló wà níbùdó ìgbókùsí, àmọ́ òkú ọmọ di àwátì

Yoruba ni gbogbo awọn to ba mọ nkan fi pamọ, ni ki wọn maa ranti ẹni to mọ wa.

Bẹẹ ni ọrọ ri pẹlu oku ọmọ ikoko to sadede di awati nibudo igbokusi to wa nile iwosan awọn ọlọpaa nilu Akurẹ́.

Oku iya ọmọ tuntun, oku ọmọ ikoko naa ati olubi rẹ ni wọn tọju pamọ sile igbokusi naa, amọ oku ọmọ yii nikan lo poora.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Ta lo wa ji oku ikoko? Awọn afurasi wo ni ọwọ ti tẹ nipa iṣẹlẹ naa, ati pe, nibo ni iwadi de duro lori iṣẹlẹ yii?

Baba ikoko naa sọ bi iku se ku, ati bi ọbẹ se bẹ nipa isẹlẹ naa, lori eto wa Kayeefi ta mu wa fun yin lọjọ Ẹ́ti, amọ, itọwo rẹ ree, ẹ gba....