AFCON 2019: Àmì ayò tí Nàíjíríà àti South Afrika gbá rèé

Aworan agbabọọlu Naijiria Chukwueze ati akẹgbẹ rẹ ọmọ South Afrika Image copyright GIUSEPPE CACACE
Àkọlé àwòrán Ẹni a ba laba ni baba

Ikọ agbabọọlu orileede Naijiria Super Eagles ti gbewuro soju ikọ Bafana Bafana ti South Africa lati tẹsiwaju ninu idije Afcon 2019 to n waye ni Egypt.

Samuel Chukwueze lo kọkọ gba bọọlu wọnu awọn South Africa ni iṣẹju kẹtadinlọgbọn ifẹswọnsẹ naa ki South Africa to da goolu pada ni iṣẹju karundinlọgọrin.

Bongani Zungu lo fi ori kan bọọlu sawọn Naijiria.

Image copyright Khaled Desouki

William Troost Ekong lo de goolu lade fun Naijiria ni iṣẹju kọkandinlaadọrun.

Ni bayi Naijiria yoo koju Algeria tabi Ivory Coast ninu abala to kangun si aṣekagba idije naa.

Nigeria 2
-
1 South Africa
Ere pari
Ẹkunrẹrẹ
Ilana ere bọọlu
Nigeria
(4-2-3-1)
South Africa
(4-3-3)
Ẹkunrẹrẹ
 • 14
  -
  Mothiba
  0 - 0
 • 27
  -
  Chukwueze
  football
  1 - 0
 • 35
  -
  Musa
  1 - 0
 • 49
  -
  Hlatshwayo
  1 - 0
 • 58
  -
  Lorch
  down
  Zwane
  up
  1 - 0
 • 62
  -
  Tau
  1 - 0
 • 71
  -
  Zungu
  football
  1 - 1
 • 75
  -
  Mkhize
  1 - 1
 • 81
  -
  Musa
  down
  Simon
  up
  1 - 1
 • 86
  -
  Mothiba
  down
  Veldwijk
  up
  1 - 1
 • 89
  -
  Troost-Ekong
  football
  2 - 1
 • 91
  -
  Iwobi
  down
  Balogun
  up
  2 - 1
Alaye ni soki lori ere bọọlu
Nigeria
South Africa
 • Bọọlu wa nikawọ mi
  39.2%
  60.8%
 • Gbigba bọọlu si oju ile
  4
  2
 • Gba bọọlu
  11
  5
 • kọna
  6
  1
 • Ṣẹ sofin
  22
  19
Awọn agbabọọlu ti wọn yan
Awọn ti wọn o kọkọ bẹrẹ
Nigeria
 • 16
  Akpeyi
 • 3
  Collins
 • 22
  Omeruo
 • 5
  Troost-Ekong
 • 20
  Awaziem
 • 18
  Iwobi
 • 7
  Musa
 • 4
  Wilfred Ndidi
 • 8
  Peter Etebo
 • 13
  Chukwueze
 • 9
  Ighalo
South Africa
 • 22
  Williams
 • 14
  Hlatshwayo
 • 5
  Mkhize
 • 2
  Mkhwanazi
 • 18
  Hlanti
 • 8
  Zungu
 • 12
  Mokotjo
 • 15
  Furman
 • 19
  Tau
 • 9
  Mothiba
 • 23
  Lorch
Awọn iyipada
 • 81
  Musa
  down
  Simon
  up
 • 91
  Iwobi
  down
  Balogun
  up
 • 58
  Lorch
  down
  Zwane
  up
 • 86
  Mothiba
  down
  Veldwijk
  up
Awọn ti wọn paarọ
 • 17
  Kalu
 • 23
  Uzoho
 • 21
  Osimhen
 • 15
  Simon
 • 19
  Ogu
 • 11
  Onyekuru
 • 10
  Mikel
 • 1
  Ezenwa
 • 14
  Paul Onuachu
 • 2
  Ola Aina
 • 12
  Shehu
 • 6
  Balogun
 • 3
  Maela
 • 7
  Maboe
 • 20
  Kekana
 • 6
  Mphahlele
 • 16
  Bvuma
 • 11
  Zwane
 • 4
  Cardoso
 • 17
  Vilakazi
 • 10
  Serero
 • 13
  Mabunda
 • 21
  Veldwijk
 • 1
  Keet