'Mo sun ẹkún kíkorò nígbà tí a kí ara wa kẹ́yìn'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Drowning: Ẹni ọdún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n àti ọmọ rẹ̀ oṣù mẹ́tàlélógún kú sómi

Ko si ẹni to rinrinajo to gbadura ko ma bọ̀.

Irinajo ti Oscar Martinez Ramirez kọ ko tẹle adura yii o. At'oun at'ọmọ ọdun mẹtalelogun lo bomi lọ ní igbiyanju wọn lati rekọja odo.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Related Topics