Bí wọ́n ṣe pa Funke Olakunrin, ọmọ bàbá Fasoranti nìyí
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Fasoranti: Dẹ́rẹ́bà tó wa ọmọ Fasoranti ṣàlàyé bí wọ́n ṣe pa Funke Olakunrin

Ọpọ lo ti sọrọ lori bi iku Funkẹ Olukọrin ṣe lọ.

Iku ọmọ Alagba Rueben Fasoranti ti da ọpọlọpọ awuyewuye Kí ló mú àwọn adarí Nàìjíríà tako ra wọn lórí ikú ọmọ alága ẹgbẹ́ Afenifere?silẹ paapaa julọ lori awọn wo gan an lo ṣiṣẹ laabi naa.

Bi ọlọpaa ti n lọgun pe awọn agbebọn ni, wọn kii ṣe darandaran Fulani, lawọn apa kan araalu naa n pariwo pe rara oOoni Ile ife, Ààrẹ Gani Adams fárígá lórí ikú ọmọ Fasoranti, awọn Fulani lo ṣiṣẹ laabi yiiǸjẹ́ ẹ mọ ohun tí igbákejì ààrẹ Yemi Osinbajo sọ nílé bàbá Fasoranti .

Amọṣa, dẹrẹba to wa ọkọ arabinrin naa lọjọ buruku eṣu gbomimu yii ba BBC News Yoruba sọrọ lori bi ọrọ ṣe ṣẹlẹ gan an.