‘Àwọn Fulani gbọ́dọ̀ kúrò ní ìpínlẹ̀ Ondo’
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Awọn ọdọ Ondo fẹ̀họ́nù hàn lórí ìṣekúpani Funke Olakunrin

Awọn ọdọ ipinlẹ Ondo n fẹhọnu han pe ki awon Fulani o kuro lagbeegbe wọn, leyin ti awọn agbebọn pa Funke Olakunri to jẹ ọmọ adari ẹgbẹ Afẹnifẹrẹ lorilẹ-ede Naijiria.

Ọpọlọpọ awọn eniyan lo ni awọn Fulani darandaran lo se isẹ ibi naa ni opopona Ore ni ipinlẹ Ondo.

Amọ awọn ọlọpaa ni awọn ọdọ naa gbe paali pẹlu orisirisi akori, ti wọn si n lọ lọwọọwọ.

Awọn ọdọ bẹrẹ ifẹhonuhan pe iku gbigbona ti to gẹẹ nipinlẹ Ondo ati ijinigbe.