2-0 ni ọ̀pọ̀ ọmọ Naijiria gbà pé Super Eagles a fún Tuniṣia lónìí
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

AFCON 2019: Ki akọnimọọgba Naijira bá wọn sọ̀rọ̀ kóríyá

Ọpọ tun yanana pé ki akọnimọọgba Naijiria ranti awọn aṣiṣe to ṣẹlẹ ninu idije to kọja.

Nigba ti BBC Yoruba fọrọ wa awọn ololufẹ Super Eagles lẹnu wo lori idije toni, ọpọ wọn lo fadura ranṣẹ si awọn agbabọọlu wa ni Egypt

Nigba ti awọn miran n fun wọn ni imọran ki wọn le bori idije wọn pẹlu orilẹ-ede Tunisia ti wọn jo n dije du ipo kẹta.