Face app: Àwọn òṣèré tíátà kan ṣàfihàn fọ́tò ọjọ́ ogbó wọn

Image copyright Woli Agba
Àkọlé àwòrán Ayọ Ajewọle asfihan bi yoo se ri tọjọ ogbo ba de
Image copyright Alamy
Àkọlé àwòrán Haa, arugbo soge ri ree o, Ọpẹyẹmi Aiyeọla lo ti yaa di iya agba yii
Image copyright Aremu Afolayan
Àkọlé àwòrán Hun, owe nla ni awọn aworan yii n pa fun ni pe ọjọ alẹ n bọ
Image copyright Laide Bakare
Àkọlé àwòrán Arugbo sogeri, ekisa logba ri ni aworan ọjọ ogbo Laide Bakare yii
Image copyright Mosunmola Filani
Àkọlé àwòrán Gbogbo ẹyin ewe, ẹmaa ranti pe agba n bọ wa kan wa
Image copyright Mike Bamiloye
Àkọlé àwòrán Ẹru si n yọ mi ba, ti mo ba ranti ọjọ ogbo, bawo ni iwọ yoo ti ri?
Image copyright Lateef Adedimeji
Àkọlé àwòrán Ọmọde ọjọun, o n dagba ree o, kori jẹ o pẹ laye, ko to agba da.
Image copyright thesolaallyson
Àkọlé àwòrán Ẹ o rii pe ẹrin gbajugbaja olorin Sola Allyson lekan sii lọjọ ogbo?
Image copyright Odunlade Adekola
Àkọlé àwòrán Ọdunlade ọmọ Adekọla, agba n bọ wa kan ọ o
Image copyright Jide Kosoko
Àkọlé àwòrán Agba kii pẹ kan ni