Látorí N50 kó tó di N500,000 ni mo ń gbà fún ẹ̀fẹ̀ n'Ibadan
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Lafup: Kò sí ẹni kankan tó ń ṣe ẹ̀fẹ̀ ní Ibadan nígbà táwa bẹ̀rẹ̀

Adẹrinpoṣonu ti ko ṣee fọwọ rọ sẹyin ni Oluwasegun Ogundipe ti gbogbo eniyan mọ si Lafup jẹ ni ilu Ibadan.

O fọwọ rẹ sọya pe ko si ẹni kankan ti o n ṣe ẹfẹ niluu Ibadan nigba ti oun fi bẹrẹ titi ti ohun fi wa di ẹni ti wọn mọ kaakiri Naijiria bayii.

Lekan kingkong lọmọ Yorùbá tó ń fi òwe dárà lẹ́yìn odi

Níbo làwọn òṣèré apanilẹ́rìn ín wọ̀nyí tó pilẹ̀ sínima àgbéléwò Yorùbá wà?

Nigba ti owo ṣi ni iyi lo ti bẹrẹ to jẹ wi pe ati san aadọta naira pere gun awọn eniyan lara ṣugbọn o jẹ ki awọn eeyan mọ iyi owo ti wọn n san nigba naa lati wa fi wo awọn ẹfẹ rẹ.

Awọn Iroyin ti ẹ le nifẹ si