Ẹ wo ìdí tí Yinka Ayefele fí ní òun kó bí ìbẹta lọ́jọ́sí
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Yinka Ayefele ni ìkómọ àwọn ìbẹ́ta òun kò tíì lè wáyé báyìí àyàfi tí òun bá gba páálí wọn l'Ámẹ́ríkà

BBC Yoruba ba gbajugbaja olorin nni to tun jẹ oludaleeṣẹ redio silẹ, Yinka Ayefẹlẹ sọrọ lati fi aridaju rẹ han pe ni bayi, o ti di baba ibẹta lootọ.

Ṣaaju ni nkan bii oṣu diẹ sẹyin ni iroyin kan tan kalẹ pe o bimọ ti o si ni irọ ni awọn eniyan n pa, Ẹ dákẹ́ àhesọ ọ̀rọ̀, n kò bí ìbẹta - Yinka Ayefẹlẹ.

Ṣugbọn ni bayii oun funra rẹ lo tu iroyin ayọ yii fun awọn oṣiṣẹ ileeṣẹ redio rẹ pe Yinka Ayefele di bàbá ìbẹta.

Lati mu aridaju wa fun yin la fi ṣe ifọrọwanilẹnuwo yii pẹlu baba ibẹta gan funra rẹ to si ṣalaye gbogbo ọrọ.

Yinka Ayefele di asojú Àjọ INEC

Ayefele fi orin ẹ ṣeun sẹ́nu kí Ajimobi

Ayefẹlẹ bá BBC sọ̀rọ̀ lórí ilé orin rẹ̀ tí Ajimọbí ń tún kọ́

Awọn Iroyin ti ẹ le nifẹ si