Oyo: Ọkùnrin mẹ́tàlá, obìnrin kan ni Makinde fi orúkọ wọn sílẹ̀

Seyi Makinde

Gomina ipinlẹ Ọyọ, Seyi Makinde ti kede ti o si fi orukọ awọn to fẹ yan si ipo kọmisana ipinlẹ naa ranṣẹ sile aṣofin.

Olori ile aṣofin ipinlẹ naa, Adebọ Ogundoyin, kede orukọ awọn eniyan naa sita l'Ọjọbọ.

Ninu orukọ mẹrinla ọhun lati ri ọkunrin mẹtala, ati obinrin kan.

Awọn orukọ naa ni:

 • Hon Barrister Adeniyi John Farito
 • Mr Adeniyi Adebisi
 • Hon Muyiwa Jacob Ojekunle
 • Prof Oyelowo Oyewo
 • Barrister Olasunkanmi Olaleye
 • Barrister Seun Asamu
 • Mr Rahman Abiodun AbdulRaheem
 • Chief Bayo Lawal
 • Hon Funmilayo Orisadeyi
 • Dr Bashir Bello
 • Hon Wasiu Olatunbosun
 • Prof Daud kehinde Sangodoyin
 • Mr Akinola Ojo
 • Rt Hon Kehinde Ayoola