''Ọjà ẹran àgbò kò yá bí ti ọdún tó lọ''
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Eid-el-Kabir: ''A ò rí èèyàn ra ẹran àgbò lọ́dún yìí bíi ọdún Iléyá tó lọ''

Ileya ti de, Ileya ti de o, Barka De Sallah ẹ ku ọdun. Pọpọsinsin ọdun Ileya bẹrẹ kaakiri orilẹede Naijiria ati lagbayee.

Ọpọ musulumi ni wọn ti ra ẹran agbo fun ayẹyẹ ọdun Ileya, ṣugbọn oniṣowo ẹran agbo ni Ojurin lagbagbe Alẹṣinlọyẹ niluu Ibadan, Ọgbẹni Fatai Ibrahim sọ fun BBC Yoruba pe awọn ẹran agbo t'oun ta ni ẹgbẹrun mẹẹdọgbọn nairia lọdun to lọ ti di ẹgbẹrun un mejilelogub bayii.

O ni idi abajọ naa ni wi pe awọn eeyan ko tu yaya jade ra ẹran bii ti ọdun Ileya to lọ.