UI: Kélé yóò gbé ọkùnrin tó bá ń rin gb;eregbére lágbègbè ibùgbé obìnrin ní fásitì Ibadan

Ogba fasiti ibadan Image copyright University of Ibadan
Àkọlé àwòrán Laipẹ yii lawọn janduku kan ya wọ ileegbe awọn obinrin lọgba fasiti naa ti wọn si ṣe ọṣẹ

Laipẹ yii ni iroyin kan pe awọn janduku kan ti ya wọ ibugbe awọn akẹkọ to jẹ obinrin ni fasiti Ibadan.

Nibayii, awọn alaṣẹ fasiti Ibadan ti wa kede ofin isede lọgba faisiti naa laarin agogo mejila oru si agogo marun idaji.

SERAP fẹ́ pe UI, AAUA lẹ́jọ́ lórí àfikún owó iléẹ̀kọ́

OAU: Ohùn ọ̀jọ̀gbọ́n Richard Akindele ni wọ́n ká sílẹ̀

Khafi wọ gàu lẹ́nu iṣẹ́ lórí ẹ̀sùn ìbálòpọ̀ ní BB Naija

Àṣìta ìbọn ló pa obìnrin nílùú Eko lọ́jọ́ Satide- Ọlọ́pàá

Lórí ìmọ̀ràn Sunday Igboho, Ẹlẹbubọn ní yóò dára kí Yorùbá padà sí àmúlò èròjà ìbílẹ̀ fún ààbò

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionCS Mum: Omotolani Ekene ní ọ̀pọ̀ èèyàn gbà pé ọ̀lẹ, arugún, aláìlera ni ẹni tó fi abẹ bímọ

Ofin yii yoo si bẹrẹ loru ọjọru.

Nibi ipade igbimọ abo ileewe naa ni wọn ti gbe igbesẹ yii.

Gẹgẹ bii atẹjade kan ti giwa fasiti naa, Ọjọgbọn Idowu Ọlayinka fi sita ṣalaye wi pe awọn alejo ọkunrin to ba fẹ bẹ awọn akẹkọbinrin ni ibugbe Awolowo hall, Queen Idia hall ati Elizabeth hall ko gbọdọ wọ inu ibugbe awọn obinrin naa ms o. Ita gbangba ni wọn yoo ti maa gbalejo wọn

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionSnake Market: Àwọn òńtàjà ẹran ejò ní ẹran ejò dùn ju ẹran adìẹ lọ

Bakan naa lo ni ọwọ afunrasi ni wọn yoo fi mu ọkunrin kankan ti o ba n rin gberegbere kaakiri ibugbe awọn obinrin nileewe naa kọja agogo mẹjọ abọ alẹ.

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionSunday Igboho: Fulani kò leè dúró, táa bá lo ohun ta jogún lọ́dọ̀ àwọ̀n bàbá wa