Ọ̀ṣun Oṣogbo 2019: Ìyán gbígbóná ní wọn kọ́ fi bẹ̀rẹ̀ ọdún

Àkọlé àwòrán Iwaju aafin ti n rọ kẹkẹ fun ọdun
Àkọlé àwòrán Ẹ poore yeeeye ooo, Ọṣun jọọ, fun wa lowo, fun wa ni ọmọ, fun wa ni alaafia
Àkọlé àwòrán Iya olomi tutu ti Osogbo naa ti setan ọdun
Àkọlé àwòrán Iyan gbigbona ni aarọ ni awọn obinrin kọkọ monuto
Àkọlé àwòrán Haa, ọrọ yii gba ki awọn ọkunrin gba odo iyan
Àkọlé àwòrán Tọmọde-tagba lo ti n ta mọra lati mura fun ọdun
Àkọlé àwòrán Bi awọn ọkunrin se n palẹmọ, naa ni awọn ọkunrin n se
Àkọlé àwòrán Aje yoo kuku bu igba jẹ́ fun awọn eeyan kan lonii
Àkọlé àwòrán Ọrọ̀ aje yii naa ko yọ awọn ọkunrin silẹ, tọkunrin-tobinrin lo n wa owo
Àkọlé àwòrán Bi esinsin ba ta firi, awa setan lati wọn lasiko ọdun ni awọn agbofinro yii n wi
Àkọlé àwòrán Ni ṣẹpẹ la wa fun ọdun Ọṣun ni ọdun yii, ọdun yii ko yẹ