Wo àwọn ohun tí o kò le è rí níbòmíràn níbi àjọ̀dún Ọ̀ṣun Òṣogbo
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Osun Osogbo festival 2019: Báwo ni àjọ̀dún Ọ̀ṣun Òṣogbo ṣe lọ lọ́dún yìí?

nnkan yan nibi ayẹyẹ Ajọdun Ọṣun Osogbo to waye nilu Osogbo, ipinlẹ Ọṣun ni ọjọ Ẹti. Ijo, ilu ati iṣẹse lo balẹ sibi ayẹyẹ naa.

Amọṣa iran ko tii pari bi ẹ ko ba tii wo awọn ohun ti oju ri wọnyii nibi ajọdun naa.