Ǹjẹ́ o mọ̀ pé orin gbígbọ́ dara fún ọpọlọ ọmọ ìkókó?
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Premature babies: Ọ̀nà tí orin gbígbọ́ fi ń ṣèrànwọ́ f'ọpọlọ ọmọ ìkókó rèé

N jẹ ẹyin mọ pe orin gbigbọ fawọn ọmọ tuntun jojolo maa n ṣe iranwọ nla fun ati dagba ọpọlọ wọn?

Awọn oluwadii kan nileewe giga fasiti ilu Geneva lo fidi rẹ mu lẹ gbigbọ orin maa ṣe atunṣe ọpọlọ awọn ọmọde.

Awọn oluwadii naa sọ siwaju pe orun orin yii maa n ran awọn ọmọ ti wọn bi nigba toṣu wọn ko tii pe lọwọ lati dagba.