Wo àwọn àwòràn tó làmìlaaka nílẹ̀ Adúláwọ̀ lọ́sẹ̀ yìí

Image copyright Reuters
Àkọlé àwòrán DJ Arafat, gbogbo Abidjan wa riri lati bu ọla fun un.

Ẹgbẹlẹgbẹ awọn eniyan ni wọn wa ṣe idaro gbajugbaja olorin n ni DJ Arafat.

Abidjan ni orilẹ-ede Ivory Caost gablejo awọn ero nibi eto isinku ọmọ ódun mẹtalelọgbọn naa to ku nibi ijamba to ni lori alupupu rẹ.

Koda, aarẹ ilẹ Ivory Coast, Alassane Quattara ati Davido gan an wa ni papa iṣere Félix Houphouet Boigny Stadium ti wọn ti ṣe ẹyẹ ikẹyin fun Arafat.

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Awọn ogbontarigii olorin ile Afrika ṣe ẹyẹ ikẹyin fun Arafat
Image copyright EPA
Àkọlé àwòrán Ọkan lara awọn to n sare fun idije agbaye ṣafihan bi eeyan ṣe le fo pẹlu ara rẹ.
Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Lọjọ Abamẹta ni Johannesburg ni awọn ti wọn n ja ti n da awọn onworan laraya.

Ni Joannesburg to jẹ olu ilu orilẹ-ede South Africa ni awọn alagbara ti n dan ara wo ti wọn n ja fawọn onworan paapaa awọn ololufẹ.

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media caption'Òṣìṣẹ́ Bánkì ni mí l'Amẹ́ríkà kí n tó bẹ̀rẹ̀ Tíátà'
Image copyright EPA
Àkọlé àwòrán Arabinrin ọmọ Somali yii, Iman lo n ṣafihan aṣọ yii ninu irin oge rẹ ni Italy.

Lọjọru to kọja ni Iman ara Somalia to n rirnrin oge wọ aṣọ alarabra yii.

O wọọ nibi ajọdun fiimu agbaye to waye ni Vernice ni orilẹ-ede Italy.

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionÌsọ̀ oníwe ìròyìn àtàwọn tó ń kà a lọ́fẹ̀ẹ́
Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Ogbontarigi osere ọmọ South Africa yii n fayọ ya fọto nipasẹ odo

Gbajugbaja oṣere, Candice Swanepoel to wa lati orilẹ-ede South Africa lo duro ya fọto ninu omi yii.

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán D Banj lo gbogo nibi eto Brixton Academy ni London.

Eyi ni ogbontarigi olorin takasufe ọmọ Naijiria, DBanj nigba to n ṣere ni ile iwe giga Brixton Academy ni London lọjọ Aiku.

O ti kọkọ sọ fun BBC pe laipẹ ni iyawo oun a to bimọ ikoko tuntunÀwọn olórin Nàìjíríà kẹ́dùn ikú ọmọ DBanj

Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Diẹ lara awọn eniyan ti wọn n ṣajọyọ ọdun Fatchue ni Ivory Coast.

Odun "Fatchue" ni ọdun ti awọn ọmọde fi n palẹmọ de ipo adari lọjọ iwaju.

Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Awon omo wonyi ti setan lati bere ikoni si ipo agba leyin odun yii
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media caption'Isẹ́ Tíátà tí mò ń se ti tó mi jẹun'
Image copyright EPA
Àkọlé àwòrán Awon omo ogun ile n so eranko yii pelu ohun gbogbo ti won ni

Ni orilẹ-ede Kenya ni a ti ri awọn ọmọ ogun ilẹ yii ti wọn n ṣo diẹ lara awọn erinmi ni Kenya.

Won n pese aabo fun eranko yii bo ṣe n wa ibi to maa ye ẹyin si lọjọ Eti to kọja.

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionFela ni awokọse mi - Kunle Ajayi