Ẹ wo àràmọ̀ǹdà ọmọ ọdún mọ́kànlá tó jẹ́ elégèé àrà tó dáńtọ́ jùlọ
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Chinonso Eche: Mo fẹ́ dà bíi Messi, Ronaldo àti Okocha

Ọmọ ti yoo ba jẹ Aṣamu, kekere ni yoo ti maa jẹ ẹnu ṣamuṣamu.

Chinonso Eche, tii se ọmọ ọdun mọkanla ree, to jẹ elege ara nilu Warri, ko si si elege to dabi rẹ.

Lati ọmọ ọdun mẹjọ ni Chinonso ti bẹrẹ ege gige, to si fẹ dabi Messi, Ronaldo ati Okocha.

O tun fẹ di ilumọọka agbabọọlu fun awọn gbajugbaja ẹgbẹ agbabọọlu agbaye bii Super Eagles ilk wa, Barcelona, Real madrid ati Chelsea.

Ẹ wo fidio yii lati mọ iru ara ti Chinonso n fi bọọlu da nidi ege gige.