Ìpéníjà owó jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú ìṣòro àwá òṣèré- Kemi Lala
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Kemi Lala: mo ń gbìyànjú láti mú inú òbí mi dùn

Orin Sola Allyson, Adekunle Gold ni mo fẹran- Kemi Lala

Sẹ ẹ ranti ere Dazzling Mirage, Alan Poza ati Suuru Lere?

Kemi Lala Akindoju to ko ipa pataki ninu awọn ere yii ba BBC lalejo.

Kemi Lala Akindoju gba awọn ọdọ nimọran lati ka iwe wọn ki bata wọn le dun kookoo ka lọjọ ọla.

Idile ọlọmọ mẹrin ni a bi Kemi Lala si nipinlẹ Ondo.

O lọ sile iwe Queens College ati Fasiti Eko ati Fasiti Pan Atlantic to ti kawe gboye imọ ijinlẹ ipele keji

Kemi Lala Akindoju rọ awọn eeyan lati ṣiṣẹ karakara pẹlu idunnu ati ayọ ki ọkan onikaluku le balẹ.