‘Ayé obìnrin tí wọ́n fipábálòpọ̀ kò lè rí bákàn náà mọ́’
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Rape: Norma Ka Mbele ní ayé òun kò rí bákàn náà mọ́ lẹ́yìn ìfipábálòpọ̀

Iwadii fihan pe Orilẹede South Africa lo ni iye obinrin ti wọn ti fipabalopọ, ti wọn si tun sekupa julọ lagbaye.

Ninu fidio yii ni Norma Ka Mbele ti salaye bi awọn ọdọ mẹta ti fipa baa lopọ, ti ileesẹ ọlọpaa ko si ri ohun kankan se si.

Bakan naa ni Norma Ka Mbele sọ wi pe, igbesi aye oun ti yi pada lati igba ti wọn ti fi ipa ba oun lopọ, nitori ko si obinrin ti wọn yoo fipa ba lopọ, ti aye rẹ yoo tun ri bakan naa mọ.