Òwe: Kí ni ìtumọ̀ òwe ikú tó ń pa ojúgbà ẹni?

Yoruba ni owe lẹsin ọrọ, bi ọrọ ba sọnu, owe la fi n wa.

Amọ o se ni laanu pe ọpọ awọn ọdọ ode iwoyi ni ko mọ awọn owe mọ, ti ọpọ awọn owe abalaye wa si n wọọkun diẹdiẹ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Idi ree ti BBC Yoruba fi lọ saarin awọn smọ Kaarọ oojire lati mọ bi wọn se gbọ Yoruba si, taa si ni ki wọn pari owe ‘Iku to n pa ojugba ẹni...’

O ya, ẹyin naa, ẹ pari rẹ, ka ;ee ms bi ẹ se gbọ Yoruba si.