Saudi Arabia mosque: Wo àwòdamiẹnu àwòrán Mọ́ṣáláṣí Ànọ́bì ní Medina!

Òpópónà Mẹ́kà mọ́ roro; àwọn èèyàn ni wọ́n n tún un ṣe to fi n rẹwà síi bi o ṣe hànde ninu awọn aworan yii.

mosalasi

Oríṣun àwòrán, @Masjid

Àkọlé àwòrán,

Aworan Mọṣalaṣi Median laarin agbegbe to wa lalẹ, ina orisirisi lo fi kun ẹwa yii! pẹlu awọn ohun to yii ka nilu to mọ lolo yii

Oríṣun àwòrán, @Masjid

Àkọlé àwòrán,

Orule mọṣalaṣi nla ti Medina ni orilẹ-ede Saudi Arabia

Oríṣun àwòrán, @Masjid

Àkọlé àwòrán,

Enu iboji oku Anobi Muhammed (SAW) bi wọn ṣe n ṣọọ titi di asiko yii

Oríṣun àwòrán, @masjid

Àkọlé àwòrán,

Awọn ina alarabara ti wọn fi ṣe ọṣọ si ara awọn òpó to di mọṣalaṣi nla naa mu

Oríṣun àwòrán, @mosjid

Àkọlé àwòrán,

Aworan orule apa kan ninu mọṣalaṣi naa ti awọn ile nlanla to kun fun itan ninu Kuran yii ka.

Oríṣun àwòrán, @mosjid

Àkọlé àwòrán,

Ina ti wọn kan ṣe si inu Raudah ti ẹwa rẹ kọja fifi riran lasan.

Oríṣun àwòrán, Masjid

Àkọlé àwòrán,

Apa ibomii ni Raudah ti awọn miran ti maa n lọ gbadura bẹ Olorun

Oríṣun àwòrán, @masjid

Àkọlé àwòrán,

Nkan miran ti awọn eniyan fẹran nipa Medina ni ọna ara ti wọn fi n pe irun ninu mọṣalaṣi naa

Oríṣun àwòrán, @masjid

Àkọlé àwòrán,

Awọn alejo to wa wo iboji anobi Muhammed (SAW)

Oríṣun àwòrán, @masjid

Àkọlé àwòrán,

Awọn olutọju mọṣalaṣi yii n ṣe itoju Rauda tọwọtọwọ ni Medina

Oríṣun àwòrán, @masjid

Àkọlé àwòrán,

Okan pataki ninu awọn ẹnu ọna mọṣalaṣi Medina ti wọn n pe ni abawọle ti Oba Fahd

Oríṣun àwòrán, @Masjid

Àkọlé àwòrán,

Aworan mọṣalaṣi Medina lati oke pẹlu awọn ohun meremere to yii ka nilu nla