Menopause: Ẹja nìkan ni ẹranko tí nǹkan oṣù rẹ̀ ń dáwọ́ dúró, yàtọ̀ sí èèyàn

Menopause: Ẹja nìkan ni ẹranko tí nǹkan oṣù rẹ̀ ń dáwọ́ dúró, yàtọ̀ sí èèyàn

Kii se ohun ajeji ki nnkan obinrin dawọ duro eyi ti ko nii se pẹlu ọjọ ori rara, bẹẹ si ni ara maa n yatọ si ara lasiko ti nkan osu ba fẹ dawọ duro.

Nnkan osu obinrin lee dawọ duro to ba ti pe ẹni ọdun marundinlaadọta si aadọta, homoonu kan ti wọn n pe ni Oestrogen si la gbọ pe o n fa idaduro nkan osu naa.

Bi eyi ba si sẹlẹ, yoo nipa lori ọpọlọ, ọkan,awọ ara, egungunisan, bi ara ti n gbona si, ti yoo si tun fa aile ri oorun sun pẹlu.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Amọ adinku lee ba awọn ipa yii ti obinrin ba n jẹ ounjẹ asara loore, to si tun n se ere idaraya bo se yẹ.

Iwadi ijinlẹ gan si fidi rẹ mulẹ pe ẹja ni ẹranko kansoso ti nnkan osu rẹ naa maa n dawọ duro gẹgẹ bii tawọn obinrin.

Wo fidio yii lati mọ bo se lee mu irọrun ba ara rẹ ti nkan osu rẹ ba dawọ duro.