AMAA 2019: Aṣọ ń pe aṣọ ránṣẹ́ lásìkò àyẹyẹ àmi ẹ̀yẹ fáwọn òṣèré tíátà

Sola Sobowale

Oríṣun àwòrán, @solasobowale

Idi isẹ ẹni laa ti mọ ni lọlẹ, ohun gbogbo si lo ni ere, ka sa maa se daada.

Gbaju gbaja osere tiata lobinrin, Sola Sobowale, ni odu rẹ kun juls lagbo awsn osere tiata lobinrin nigba ti o gba ami ẹyẹ osere tiata obinrin to pegede julọ.

Sobowale gba ami ẹyẹ naa lasiko ayẹyẹ fifi ami ẹyẹ da awọn osere tiata to se gudugudu meje ati yaya mẹfa ninu ere tiata lọla, ti wọn n pe ni AMAA 2019.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Loju opo Instagram rẹ, olorire alami ẹyẹ naa, Sola Sobowale ti ki ara rẹ ku oriire, tawsn eeyan naa si n ba yọ pẹlu.

Bakan naa ni Adesua Etomi gba ami ẹyẹ obinrin to pegede sikeji lasiko ayẹyẹ ifami ẹyẹ danilọla AMAA naa, ikẹẹdogun iru rẹ.

Oríṣun àwòrán, @adeesuaetomi

Wayi o, ẹnu ko gba iroyin lori oniruuru asọ alarabara tawọn gbajumọ osere tiata wọ lọ sibi ayẹyẹ ifamiẹyẹ danilọla naa, ti asọ si n pe asọ ransẹ nibẹ.

Oríṣun àwòrán, @AMAAWARDS

Oríṣun àwòrán, @AMAAWARDS

Oríṣun àwòrán, @AMAAWARDS