Ibadan Torture House: Àṣírí ilé ìmúni nígbèkùn míràn tú síta ni Ibadan

Bi egbirin ọtẹ lọrọ awọn onile igbekun ni Naijiria yi fẹ jẹ pẹlu bi ọwọ awọn ọlọpaa nilu Ibadan ti ṣe tẹ eeyan mẹrin ti wọn ko awọn eeyan ni igbekun.

Ni adugbo ọjọ nilu Ibadan ni Komisana ọlọpaa nilu Ibadan ti ṣe afihan awọn eeyan to n dari awọn ile igbekun yi fawọn akọroyin.

Eeyan okòólénígba àti marùn ún ni wọn tu silẹ ninu la si ti ri kunrin