Ibadan Torture House: Seyi Makinde ṣe àbẹ̀wò sí ibùdó ìtọ́jú èèyàn 200 tí ọlọ́pàá tú sílẹ̀ ní ilé Ọlọ́rẹ

Ẹnikan ti wọn mu nigbekun Image copyright Others

Gomina ipinlẹ Ọyọ, Seyi Makinde ti se abẹwo si ile Ọlọrẹ to wa ni adugbo Ọjọọ nilu Ibadan loni.

Bẹẹ ba gbagbe, ile yii ni ọwọ awọn ọlọpa ti tẹ eeyan mẹrin ti wọn ko awọn eeyan ni igbekun lọjọ Aje.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Eeyan okòólénígba àti marùn ún ni wọn tu silẹ ninu ile naa, ti wọn tun n lo bii mọsalasi.

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionIbadan Torture House:Àṣírí ilé ìmúni nígbèkùn míràn tú síta ni Katsina

Lasiko to se abẹwo sibi isẹlẹ naa si ni gomina Makinde ti pasẹ pe ki wọn wo Mọsalasi ọhun patapata.

Image copyright Seyi Makinde

Bakan naa lo tun se abẹwo si ibudo ti wọn ti n se itọju awọn eeyan ti wọn tu silẹ ninu igbekun ni mọsalasi ọhun.