Mo bọ́ lọ́wọ́ igbó mímu ṣùgbọ́n ìnira ilé Aafa Ọlọrẹ ti pọ̀jù- ọ̀dọ́ kan
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Illegal Rehab Centre: A le ni ogójì tí wọ́n n kó sinú ìyará kékeré kan níle Ọlọrẹ

Wọn mu mi wa sibi nitori pe mo n mu siga- ọmọbinrin kan.

Leyin ti gomina Seyi Makinde ti ko awọn eeyan to wa ni imuninigbekun kuro lọdọ Aafa Olọrẹ nitosi Ọjọọ nilu Ibadan nipinlẹ Ọyọ Ẹ̀yin òbí, ẹ má kó àwọn ọmọ yín lọ síbùdó atúnwàṣe mọ́ - Seyi Makinde ni BBC ṣabẹwo sibẹ.

Kekere kọ nike Ramọ ni oun ti oju awọn eeyan n ri nile yii.Àṣírí ígbèkùn nílé Olore n‘Ibadan kìí ṣe tuntun, ó ti kọ́ wáyé ní 2008

Oriṣiiriṣii ẹsun ni awọn ọdọ ti wọn ko sinu ile ibaniwi yii fi kan Aafa Olore atawọn to n tọju wọn nibẹ.

Sibẹ awọn miran ninu wọn gba pe iyatọ ti de ba igbesi aye awọn nitori pe ti iya ba to iya fọmọde, o maa yipada ni tipa ni.