Wo ìlú tí wan tí ń ta ọmọ ọ̀dọ̀ lórí ayélujára
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Online Slave Market: Wo ìlú tí wọ́n tí ta ọmọdé àti obìnrin ṣe káràtátà lórí ayélujára

Ara mee riri, mo rori ologbo latẹ. Lẹyin ọpọlọpọ ọdun ti owo ẹru ti pari lagbaye, lawọn eeyan kan lorilẹede Kuwait tun ṣe fi ọmọ ọdọ ati obinrin ṣe karata bayii.

Amọ, ori ayelujara ni wọn ti n ṣee, wọn polowo ọmọ ọdun pẹlu ọkọ ati ẹrọ amunawa lori ẹrọ ayelujara.

Awọn obinrin miiran ko tilẹ mọ pe wọn ta awọn lori ayelujara

Ẹnikan to n lo ẹrọ naa ta ọmọ fun miliọnu kan ati ẹgbẹrun un lọna ọdunrun un naira, $3,800

Ati wi pe awọn ọlọpaa n ran wa lọwọ lati ru ofin.

Ẹrọ 4Sale, Haraj ati Instagram faye silẹ fun awọn to ni ọmọọdọ lati tawọn eniyan yii fun ẹlomiran fun ere ti wọn.

Karakata yii kii ṣe ohun to ba ofin mu nitori o fi aye silẹ fun ṣiṣe ọmọde atawọn obinrin baṣubaṣu.

Facebook to ni Instagram ti fofin de owo ẹru lori Instagram, wọn si ti yọ oju opo eniyan 703 lẹyin iwadii.