Àwọn Agbẹjọ́rò Makinde àti Adelabu sọ́rọ́ nípa ìdájọ
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ọ̀rọ̀ rèè láti ẹnu àwọn Agbẹjọ́rò Makinde àti Adelabu nípa ìdájọ ọ́rọ́ ìdìbò Gómìnà Oyo

Yatọ si ọrọ tawọn ọmọ Naijiria n sọ loju opo Twitter awọn agbẹjọro fawọn oludije mejeeji ti ọrọ igbẹjọ idibo Gomina ipinlẹ Oyo kan naa sọ ti wọn.

Kete ti wọn jade lati inu ile ẹjọ ni wọn ṣalaye fawọn oniroyin oun to kan lẹyin tawọn adajọ sọ ti wọn.

Ẹkunrẹrẹ fidio naa la fi soke yi ki ẹ ba le mọ bi ọrọ naa ti ṣe n lọ.

Ọpọ awọn eniyan lo ti n sọrọ lori ayelujara pe idajọ naa ri ba kan ba kan.

Koko kan ṣoṣo to daju ni pe ipade awọn mejeeji di ile ẹjọ giga julọ.