Kogi àti Bayelsa: Èsì tó jáde láti ìpínlẹ̀ Kogi

Gomina Yahaya Bello Image copyright Aseda Sunny Aseda

Ìròyìn tó ń tẹ̀ wa lọ́wọ́lọ́wọ́ ní wí pé àjọ INEC ìpínlẹ̀ Kogi ti bẹ̀rẹ̀ si ni kédé èsì ìdìbò gómìnà ti ìjọba ìbílẹ̀ tó kù ṣáájú kíkéde ẹni tó jáwé olúborí.

Bo ṣe ń jáde rèé.

KOGI

Èsì ìdìbò sípò Kogi lórílẹ̀èdè Nàíjíríà

So awé yìí di tuntun láti rí awọn èsì tó ṣẹ́sẹ̀ dé
Máápù èsì ìpínlẹ̀

Àjọ INEC so ìbò kíkà ní ìpínlẹ̀ Kogi rọ̀ dí aago mẹ́sàn án àárọ̀ ọjọ́ Ajé

BAYELSA

Èsì ìdìbò sípò Bayelsa lórílẹ̀èdè Nàíjíríà

So awé yìí di tuntun láti rí awọn èsì tó ṣẹ́sẹ̀ dé
Máápù èsì ìpínlẹ̀

A n se akojọpọ ẹkunrẹrẹ iroyin yajoyajo lọwọ, a o maa gbe ẹkunrẹrẹ iroyin naa sori atẹ iroyin wa laipẹ. Ẹ jọwọ, ẹ tun oju opo iroyin yi yẹwo, ki ẹ lee ri ẹkunrẹrẹ iroyin ọtun laipẹ.