'Iṣẹ́ akólẹ̀ tí mò ń ṣe níbí, mi ò lè ṣe é láí lái ní Nàìjíríà tórí...'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Immigration: Bàyìí ni iṣẹ́ ajé ṣe sọ àwọn ọmọ Nàìjíríà nù sí London

Owe Yoruba to ni ajo ko da bii ile, ile labọ isimi oko naa lo tun ni ooṣa boo le gbe mi ṣe mi boo ṣe ba mi.

Eyi lo difa fun awọn ọmọ orilẹede Naijiria to ti fi ilu kan ni London ṣe ibugbe fun ọjọ pipẹ, Peckham.

'Ojú mi rí tóó, àwọn ìyàwó kìí ṣiṣẹ́, ọkọ àtàwa ọmọ-ọ̀dọ̀ laláṣekú lórílẹ̀èdè Oman'

Ǹjẹ́ ẹ mọ̀ pé Cameroon ni wọ́n ti ru Kìnìhún VI wá?

Peckham jẹ agbegbe kan ti o kun fun ọpọlọpọ ọmọ Naijiria atawọn ọmọ ilẹ adulawọ mii.

Bi o tilẹ jẹ pe ko si irufẹ ounjẹ ilẹ Naijiria ti ẹ o le ri ra nibẹ tabi lọ jẹ, ọpọ wọn ṣi ni ko da bii ki awọn maa jẹ Amala, Iyan, Ẹfọ ati bẹẹ bẹẹ lọ ni ilu ibi awọn lorilẹede Naijiria.

Tori eyi, akọroyin BBC Yoruba to ṣabẹwo si ilu Peckham ni London ba wọn ni gbolohun awọn kan "lailai ajo ko le da bii ile, ile koko n tagbe" bi awọn ba ti ko ọrọ̀ jọ tan ni ilu London.