Àdúrà là ń gbà kí à lè jèrè Yahaya Bello ní ìpadàbọ̀ rẹ̀- ará ìlú
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Kogi 2019: Àwọn ará ìlú sọ̀rọ̀ lórí ìrètí wọn lọ́wọ́ Yahaya Bello

Owo oṣu oṣiṣẹ lasiko ati ọrọ awọn olọja ṣe koko ni a n fẹ - ara ilu Kogi

Lẹyin idibo ọjọ satide, ọjọ kerindinlogun. oṣu kọkanla ọdun yii ni ajọ eleto idibo INEC kede pe Yahahya Bello lo wọle lẹẹkan sii ni ipinlẹ Kogi.

Awọn eniyan ipinlẹ Kogi ṣalaye ni kikun ohun ti wọn n reti lọwọ gomina tuntun, Yahaya Bello ni ipadabọ rẹ lẹẹkeji yii.