Ẹ wo fídíò Kìnìhún ní ibùgbé rẹ̀ tuntun ní Bogije, Lekki
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Lagos Lion: Kìnìhún ti jí lẹ́yìn abẹ́rẹ́ orun méjì tí wọ́n yìn lù ú

Nibi yii ni ibugbe tuntun ti wọn gbe Kinihun ti awọn ara adugbo figbe ta pe awọn ko fẹ layika awọn si.

Gbogbo ọrọ nipa Kinihun yii

Ṣugbọn nigba ti awọn ara adugbo figbe ta, igbimọ amuṣẹya fun ajọ alatunṣe agbegbe ni ìpínle Eko, Lagos Environmental Sanitation & Special Offences mu iṣẹ ṣe ni wara n sesa lati lọ gbe e kuro ni ile naa ki ọrọ to di idakeji rẹ.

Ọta oogun orun meji ni wọn yin si i lara lati ọọkan lati le gbe e kuro ninu ile naa wọn si gbe e kanmọkanmọ lọ si ọgba awọn ẹranko inu igbo ni Bogijẹ Omu Zoo ni Lekki, ipinlẹ Eko.