Ondo disability: Kò sí ẹni tí àkàndá kò lè ya ilé rẹ̀- Ayọdele
Ondo disability: Kò sí ẹni tí àkàndá kò lè ya ilé rẹ̀- Ayọdele
Oriṣii ọna ni Akanda ṣe wa ni ayé ẹda- Folajogun
Awọn akanda ẹda ni ipinlẹ Ondo sọrọ ni kikun lori àwọn nkan ti oju wọn n ri lọkunrin lobinrin lawujọ.
Folajogun Akinlami to jẹ ajafẹtọọ akanda to tun n dari ajọ Differently Able Foundation to jẹ ajọ to n tọju awọn ewe ti wọn jẹ akanda ẹ da naa sọrọ lori ipenija wọn fun BBC.
- Uganda ti bẹrẹ ìgbésè láti fi ikú ṣefàjẹ fún ẹní bá ṣe ìgbéyàwó akọ si akọ ati abo si abo
- Okunrin kan kú lójijì lẹ̀yin ọjọ̀ díẹ̀ to jẹ milionu kan dọ́là
- 'Títẹ àwọn afipábánilopọ̀ lọ́dàá kọ́ ni ọ̀nà àbáyọ sí ìwà ìfipábánilopọ̀'
- Ọdọ́bìnrin kan dáná sun ara rẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ ìfẹ́
- Wo àwọn ọtí ẹlẹ́rìndòdò tó ń fa àrùn jẹjẹrẹ...
Fagorola Ayodele to jẹ alaga fawọn aafin ni ipinlẹ Ondo naa mẹnuba idẹyẹsi ti aafin n koju kaakiri Naijiria.
Ariṣe Fọlaṣade to n ṣoju ijọba Ondo fawọn akanda ẹda naa sọrọ lori ọna abayọ si iṣoro awọn akanda ni Naijiria.
Abajade ifẹsẹmulẹ fawọn ofin to n gbeja akanda ẹda lo yẹ ki ijọba gbajumọ bẹrẹ lati ibilẹ si ijọba ipinlẹ titi de ori ijọba apapọ.
Gbogbo wọn gbagbọ pe eyi yoo jẹ ki aye tubọ rọrun sii fawọn akanda ẹda.