Ankara Design: Ai ri oníbàárà ló jẹ́ kí n wá ọ̀gbọ́n àtinúdá tèmi.
Ankara Design: Ai ri oníbàárà ló jẹ́ kí n wá ọ̀gbọ́n àtinúdá tèmi.
Ankara to jẹ ọkan lara awọn aṣọ iṣẹmbaye Yoruba di ohun amuyangan kaakiri agbaye bayii.
Ara ti awọn aranṣọ, aṣebata, ẹgba ọwọ ati run ọṣọ ile ati ita koda to fi mọ awọn ohun mere mere airotẹlẹ ko ṣee fẹnu sọ.
- Coronavirus: Ǹjẹ́ àwọn dókítà tó ń tọ́jú eyín ń ṣisẹ́ lásìkò pàjáwìrì? Àti àwọn ìbéèrè míràn
- Sola Sobowale gbàmì ẹ̀yẹ òṣèré tíátà obìnrin tó dáńtọ́ jùlọ
- Akẹ́kọ̀ọ́gboyè ní mí ṣùgbọ́n aṣọ òké ló ń pawó wọlé'
- Lẹ́yìn ìfẹ̀yìntì ọdún márùn-ún, báágì àti bàtà ló kàn
- Àwọn òṣèré tíátà kan rèé, tí wọn fẹ́ ara wọn, tí ìgbeyàwó wọn sì pẹ́
Aṣe aṣọ loge ni arabinrin Temitope Ojo ṣugbọn lọna ọtọ ni itan tirẹ gba yọ.
Temitope ni ohun lohun kọkọ bẹrẹ si ni fi awọn ageku ankara ya aworan sara aṣọ.
BBC Yoruba ba a ni gbolohun lori ipenija to ti ni ko to gun akasọ de bi aṣeyọri to wa bayii.
Produced by: Yemisi Oyedepo