Super touch: Roller Blader ni mí láti ọdún mẹ́jọ sẹ́yìn

Super touch: Roller Blader ni mí láti ọdún mẹ́jọ sẹ́yìn

Ọpọ igba ni mo ti ṣubu sẹyin- Omotosho Samson

Samson Omotosho ti ọpọ maa n pe ni Super Touch Roller Blader ṣalaye fun BBC pe iṣubu oun maa n kọ oun lẹkọọ sii nipa ere idaraya ti oun yan laayo ni.

Ati tọmọde-tagba ni oun maa n da lẹkọ lori ere idaraya naa ni Naijiria.

Samson Ọmọtọṣọ mẹnuba oriṣi ẹka ere idaraya 'Skating' to wa lasiko yii ati awọn igbesẹ inu ṣiṣe wón.

Bakan naa lo sọrọ lori bi Baba ati Iya rẹ ṣe gba kamu lori ọrọ naa ti wọn si n pese atilẹyin to yẹ fun oun.

Produced by: Joshua Akinyemi