Cerebral Palsy: Ìyá Najeebah ní oyún oṣù mẹ́rin ààbọ ni wọn gbe jáde kúrò nínú òun tó di ọmọ

Àkọlé fídíò,

Cerebral Palsy: Ìyá Najeebah ní oyún oṣù mẹ́rin ààbọ ni wọn gbe jáde kúrò nínú òun

Isẹ kekere kọ ni ki eeyan tọju ọmọ to dape ninu ẹmi, ara ati ọpọlọ, ka ma sẹsẹ sọ eyi ti ko pe rara.

Lasiko to n ba BBC sọrọ iya Najeebah ni igba ti oyun inu oun n mu ewu dani ni wọn gbe jade losu mẹrin aabọ, to si wa ninu igo fun osu mẹsan, bẹẹ lo wa lẹsẹ kan aye, ẹsẹ kan ọrun fun osu mẹfa gbako.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Najeebah ti pe ọdun mẹrindinlogun bayii, to si ni isẹ ayaworan lo wu oun lati se.

Ọrọ pọ ninu fidi yii, o ya, ẹ woo.