Ìpínlẹ̀ Osun yóò mú àyípadà bá àwọn ilànà ìṣèjọba Rauf Aregbesola

Awon akekọ Osun

Oríṣun àwòrán, others

Àkọlé àwòrán,

Ipinlẹ Osun yóò mu àyípada ba àwọn ilànà ìṣejọba Aregbesola

Gómìnà ìpínlẹ̀ Osun Gboyega Oyetola ni gbogbo ètò ti tò láti fi òpin si ọ́rọ́ àṣọ ilé iwé fun gbogbo àkẹkọọ ìpínlẹ̀ Osun eyi to ti n da awuyewuye silẹ láti ọdun 2013, nígba ti Ọgbẹ́ni Rauf Aregbesola ti wà lóri oye bíi gómìnà.

Lára ìgbésl yìí, tí tún àwọn ilé iwé kọ àti ìdáduro ilé iwe ọkùnrin níkàn tàbi ilé iwé obinrin nikan ti wọ́n fi òpin sí tẹ́lẹ̀ wà lári koko mẹ́rindinlọgbọ̀n ti ìjọba Gomina Oyetola yóò múgbọ̀.

Àwọn ǹkan agbéyẹwò míràn ni Ọpọ́n ìmọ, gbigba iwe eri ile iwe alakọbẹrẹ, yiyi orukọ Fasiti Ladoke Akintola (LAUTECH) pada lara awọn akanṣe eto ti Ọgbẹni Rauf gbe kalẹ nigba naa lọhun.

Àkọlé fídíò,

Àwọn oṣiṣẹ feyinti ni Osun ṣé iwọde

Oríṣun àwòrán, others

Àkọlé àwòrán,

Ipinlẹ Osun yóò mu àyípada ba àwọn ilànà ìṣejọba Aregbesola

Ọ̀pọ̀ àwọn atunṣe yìí ni àwọn ènìyan ni o wáye nitori pé ọ̀pọ̀ ara ilú, awon ọjọgbọ́n ati àwọn to ni ilé iwé lo n pariwo lori àwọn eto ijọba to wa nilẹ̀ tẹ́lẹ̀ lori bi ko ṣe bara mu.

Tí ẹ o ba gbàgbé ni ọjọ karun oṣu kẹwàá ọdunn 2013 ni Aregbẹsola to jẹ gomina ipnll Osuin nígbà náà farahan nibi idasilẹ ile iwe alakọbẹrẹ Salvation Army Osogbo ninu asọ ilé iwé tuntun to si ni awokọṣe ni oun ati igbakeji òun jẹ fun àwọn ilé Eko jakejado ipinlẹ Osun