Oman Returnees: Ọ̀kan lára àwọn obìnrin méjèèjì ní òun ṣiṣẹ́ ọdún kan láì mú ₦5 padà wálé

Oman Returnees: Ọ̀kan lára àwọn obìnrin méjèèjì ní òun ṣiṣẹ́ ọdún kan láì mú ₦5 padà wálé

Awọn obinrin meji ree ti wọn lọ fi wọn sọfa ni orilẹede Oman, nibi ti oju wọn ti ri mabo.

Damilola Falodun ati Oyinlola Solanke ni ko rọrun lati ni ominira ni Oman lai jẹ pe obinrin ba ọga rẹ sun, ti awọn mejeeji si salaye itu ti awọn ọga wọn fi wọn pa lọhun.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Bakan naa ni wọn fẹsun kan ọpọ awọn osisẹ asọbode to wa ni papakọ ofurufu Naijiria pe, wọn n lẹdi apo pọ mọ awọn to n ko awọn obinrin lọ sowo ẹrun lawọn orilẹede Larubawa.

Ẹkunrẹrẹ ohun ti oju awọn obinrin mejeeji naa ri ni orilẹede Oman ree.

Producer Yemisi Oyedepo àti Bayo Odukoya