Pa Kasumu: Lere Paimo ní àìrìríjẹ́, àìrímú tàbí ìrònú má a ń jẹ́ kí ọjọ́ ogbó dagun

Pa Kasumu: Lere Paimo ní àìrìríjẹ́, àìrímú tàbí ìrònú má a ń jẹ́ kí ọjọ́ ogbó dagun

Ilumọọka agba ọjẹ nidi isẹ tiata, Lere Paimọ ti salaye pe lọ́pọ̀ ìgbà, àìrìríjẹ́, àìrímú tàbí ìrònú má a ń jẹ́ kí ọjọ́ ogbó dagun.

Lasiko to n ba BBC Yoruba sọrọ lori iku to pa agba ọjẹ ninu tiata miran, Pa Kasumu, Paimọ ni ó yẹ kí àgbàlagbà máa rí àánú gbà, lati ọdọ awọn eeyan awujọ, kìí ṣepé èèyàn ń tọrọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Agba ọjẹ ninu isẹ tiata naa ni omijé bọ́ lójú òun nígbà tóun rí olóògbé náà gbẹ̀yìn, nitori ipo to wa.