Coronavirus: Ètò Làá hàn mí yìí ló ń kìlọ̀ fún wa láti mú ìmọ́tótó ní pàtàkì, ká le è dènà Coronavirus

Àkọlé fídíò,

Làá hàn mí: Ètò yìí ló ń kìlọ̀ fún wa láti mú ìmọ́tótó ní pàtàkì láti dènà Coronavirus

Yoruba ni igi gogoro ma gun mi loju, ati okeere laa ti lọ̀, bẹ́ẹ́ si ni ati okeere ni oloju jinjin ti n mu ẹ́kun sun.

Idi ree ti BBC Yoruba, lori eto Laa han mi se n la wa lọyẹ lori awọn ohun to yẹ́ ka se lati dena itankalẹ arun Coronavirus.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Eto naa gba wa nimọran lati yẹra fun ọpọ ero, ka mu imọtoto ni pataki, ka maa se ounjẹ wa jinna daadaa, ka si joko sile, ti ara wa ko ba da.

Ẹ wo fidio yii lati mọ si nipa arun asekupani Coronavirus ati ba se lee bọ lọwọ rẹ.